Ìjátúyì

Sísọ síta



Ìtumọọ Ìjátúyì

Ìja is worthy of honor



Àwọn àlàyé mìíràn

Ìja or Ùja is a hunting deity regarded as the brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sì (Ẹ̀ṣọ́ùsì)



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ìja-tó-uyì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ìja - Ìja, deity of hunting
- suffice for, enough for
uyì - honor, prestige, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
ONDO
OWO



Irúurú

Túyì