Ifáfọláhàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ifáfọláhàn

Ifá displays success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-fi-ọlá-hàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination/priesthood/corpus
fi...hàn - show, display, exhibit, exhume
ọlá - success, notability, wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA
OTHERS



Irúurú

Fáfọláhàn

Fọláhàn