Jẹ́nyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Jẹ́nyọ̀

Let/make me rejoice. Permit me joy.



Àwọn àlàyé mìíràn

A shortened form of Olúwajẹ́nyọ̀ or Fájẹ́nyọ̀ or Ògúnjẹ́nyọ̀, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

jẹ́-n-yọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

jẹ́ - let
n - me (mi)
yọ̀ - rejoice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE