Jésùfọlábòmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Jésùfọlábòmí
Jesus covers me in success, notability.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a made-up Christian name. See also: Fọlábòmí.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
jésù-fi-ọlá-bò-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
jésù - Jesusfi - use
ọlá - success, notability
bò - cover
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL