Kúmápàyí

Sísọ síta



Ìtumọọ Kúmápàyí

Death should not kill this (child).



Àwọn àlàyé mìíràn

This name is given to a child in the olden days to prevent a child from dying if the mother had had previous child dying (Abiku). The full name is Kíkúmápàyí - death should not kill this.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ki-ikú-má-pa-èyí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kí - that
ikú - death
má - not
pa - kill
èyí - this (one)