Lútiṣekú

Sísọ síta



Ìtumọọ Lútiṣekú

Likely a version of "Olúṣekún"



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-ti-ṣe-kún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one, God (Olúwa)
ti - has
ṣe - make, create (something good)
kún - in addition to, fulfillment


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Olúṣekún

Olútiṣekún

Lútiṣekún