Mádémọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Mádémọ́lá

Adds royalty to nobility/success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mú-adé-mọ́-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- to use; to hold (onto); to make, to bring, select
adé - crown, royalty
mọ́ - to
ọlá - wealth, nobility, success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
OSUN



Irúurú

Mádé

Mọ́lá