Moníláárí
Sísọ síta
Ìtumọọ Moníláárí
I have significance.
Àwọn àlàyé mìíràn
It is a self adulative verb, which people use to establish their indispensability in the society. "láárí" connotes wealth, intellect, wisdom, usefulness, and high esteem.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-ní-láárí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Iní - have, own; in
láárí - significance, high esteem
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL