Mońjọrẹolúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Mońjọrẹolúwa
I'm enjoying the goodness of God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-ń-jẹ-ọrẹ-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Iń - continue to
jẹ - eat, enjoy
ọrẹ - gift, sacrifice, goodness
olúwa - lord, God
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
GENERAL                    
