Nírètíọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Nírètíọlá

In expectation of success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ní-ìrètí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ní - in
ìrètí - hope, expectation
ọlá - success, wealth, etc


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL