Odùtúgà
Sísọ síta
Ìtumọọ Odùtúgà
1. Ifá is worthy of the throne. 2. Ifá repaired the throne. (A shortened form of Odùtúgàṣe)
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
odù-tó-ùgà, odù-tún...ṣe-ugà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifátó - suffice for
ùgà - throne, position, prominence
tún...ṣe - fixes, repair
ugà - throne (igà)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU