Olúsúnmibọ́lá

Sísọ sítaÌtumọọ Olúsúnmibọ́lá

God has moved me closer to success.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-sún-mi-bá-ọláÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - lord, God
sún - move
mi - me
bá - meet
ọlá - wealth, success


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITIÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Olúsúnmbọ́lá, Súnmbọ́lá, Súnmibọ́láẸ tún wo