Olúwáfiyìsìkẹ́mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwáfiyìsìkẹ́mi

God pampers me with honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwá-fi-iyì-ṣe-ìkẹ́-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwá - Lord, God
fi - use
iyì - value, worth, honour, goodwill
ṣe - make, do, perform
ìkẹ́ - care, love, pampering
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Olúwáfiyìṣèkẹ́mi

Fiyìṣìkẹ́mi

Ṣèkẹ́mi

Ṣìkẹ́mi