Olúwátitófúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwátitófúnmi

God is enough for me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-ti-tó-fún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
ti - has
- sufficient enough for
fún - to give to
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO



Irúurú

Tófúnmi

Titó