Olúwátówánílọ́ba

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwátówánílọ́ba

God is enough for us as king.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-tó-wa-ní-ní-ọba



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
- sufficient enough for
wa - us
- have
ọba - kingship, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU