Omídélé
Sísọ síta
Ìtumọọ Omídélé
Water (in form of this child) has arrived home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
omi-dé-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
omi - water, riverdé - arrive, reach (destination)
ilé - house, home
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
GENERAL                    
