Omítókí

Sísọ síta



Ìtumọọ Omítókí

Ọ̀ṣun is worthy of praise.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

omi-tó-kí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

omi - water (the totem of the goddess Ọ̀ṣun)
- sufficient enough for
- praise


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN



Irúurú

Tókí