Oròladé
Sísọ síta
Ìtumọọ Oròladé
Orò is a crown; Orò is what we have worn (as a crown).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
orò-ni-adé, orò-ni-a-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
orò - deity of bullroarers, peace, justice, and securityni - is
adé - crown, royalty
a - we, someone who
dé - to wear
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN