Oreọ̀fẹ́tijésùnimí
Sísọ síta
Ìtumọọ Oreọ̀fẹ́tijésùnimí
I'm the grace of Jesus.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oore-ọ̀fẹ́-ti-jésù-ni-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oore - goodness, gift, benevolence, favourọ̀fẹ́ - free
ti - belonging to
jésù - Jesus
ni - is
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO