Owótọ́mọ

Sísọ sítaÌtumọọ Owótọ́mọ

Money isn't as important as the child.Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

owó-kò-tó-ọmọÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

owó - money
kò tó - is not as big/prominent as
ọmọ - child


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL