Oyèbọ̀wálé
Sísọ síta
Ìtumọọ Oyèbọ̀wálé
Honor has come back home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oyè-bọ̀-wá-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oyè - chieftaincy title, honorbọ̀ - to return
wá - to find, to come
ilé - house
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL