Púpọ̀lọpẹ́olúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Púpọ̀lọpẹ́olúwa

God's appreciation/grace is plenteous.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

púpọ̀-ni-ọpẹ́-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

púpọ̀ - abundance, plenty
ni - is
ọpẹ́ - appreciation, praise, thanks
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN