Rerelolú

Sísọ síta



Ìtumọọ Rerelolú

Good is the lord.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

rere-ni-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

rere - goodness
ni - is
olú - prominent one, lord, olúwa


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL