Ṣómẹ́fun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣómẹ́fun

The fertility god picks up chalk/purity.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-mú-ẹfun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - the fertility god (òrìṣà oko)
mú - pick, select
ẹfun - chalk


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Shómẹ́fun

Oṣómẹ́fun