Shóbọ̀wálé

Sísọ síta



Ìtumọọ Shóbọ̀wálé

A variant of Ṣóbọ̀wálé, the sorcerer has returned home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ṣó-bọ̀-wá-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣó - sorcerer, fertility god (Òrìṣà Oko)
bọ̀ - return, arrive
- come, arrive
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Ṣóbọ̀wálé

Oṣóbọ̀wálé