Similólúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Similólúwa
Rest in God.
Àwọn àlàyé mìíràn
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
sinmi-lé-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
simi/sinmi - restlé - on
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Ibi tí a ti lè kà síi
Irúurú
Sinmi, Simi, Similólú, Sinmilólú