Ṣóbáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣóbáyọ̀
The sorcerer met joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-bá-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertilitybá - meet
ayọ̀ - joy, happiness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS