Ṣóbáyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣóbáyọ̀

The sorcerer met joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣó-bá-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertility
- meet
ayọ̀ - joy, happiness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Ṣóbáyọ̀

Shóbáyọ̀

Oṣóbáyọ̀