Ṣótimírìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ṣótimírìn
The wizard has started walking.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oṣó-ti-mú-ìrìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oṣó - sorcerer, òrìṣà oko, the god of fertilityti - has
mú - pick, carry, hold
ìrìn - walk
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU