Ugbódín

Sísọ síta



Ìtumọọ Ugbódín

The bush/forest has grown so close together, we can't get in (to bury a dead child).



Àwọn àlàyé mìíràn

An Abiku name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ugbó-dín



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ugbó - igbó, forest
dín - be closed, blocked


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
OKITIPUPA
ONDO