Gbàjàbíàmílà

Sísọ síta



Ìtumọọ Gbàjàbíàmílà

One who, while fighting, pretends to be separating a fight.



Àwọn àlàyé mìíràn

A cognomen.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(a)-gba-ìjà-bí-a-mí-là



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbà - take on
ìjà - fighting, quarrel
bí - like
a - one who
mí - is
là - separate


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

1. Fẹmi Gbàjàbíamílà, Nigerian lawyer and politician. 2. Muhammed-Kabeer Olanrewaju Gbaja-Biamila, Sr,. former American football defensive https://en.wikipedia.org/wiki/Kabeer_Gbaja-Biamila



Ibi tí a ti lè kà síi

https://en.wikipedia.org/wiki/Femi_Gbaja_Biamila



Irúurú



Ẹ tún wo