Oṣùọlálé

Sísọ sítaÌtumọọ Oṣùọlálé

The season of glory has arrived.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oṣù-ọlá-léÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oṣù - month, season
ọlá - nobility, wealth, glory, prominence
lé - be ready, be timely


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurúẸ tún wo