Ọlọ́finlúà

Sísọ sítaÌtumọọ Ọlọ́finlúà

The (child of) Ọlọ́fin has character. [verification needed]Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́fin-ní-ùwàÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́fin - the title of the king of Ìṣẹri
ní - have
ùwà - character, integrity


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO
EKITIÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Tèmítáyọ̀ Ọlọ́finlúà, writer.Ibi tí a ti lè kà síiIrúurúẸ tún wo