Ọmọ́juwàgbé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́juwàgbé

The child won't let one's legacy go to waste.



Àwọn àlàyé mìíràn



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-kìí-jẹ́-kí-ìwà-gbé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
kìí - will not
jẹ́ - let
ìwà - character, legacy
gbé - go to waste


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Ọmọ́juwà



Ẹ tún wo